July 30–August 5
Lúùkù 14-16
Orin 125 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àpèjúwe Ọmọ Tó Sọ Nù”: (10 min.)
Lk 15:11-16—Ọmọ kan tó yàyàkuyà ná dúkìá rẹ̀ ní ìná àpà nípa gbígbé ìgbésí ayé oníwà wọ̀bìà (“Ọkùnrin kan ní ọmọkùnrin méjì,” “Èyí àbúrò nínú wọn,” “lo dúkìá rẹ̀ ní ìlò àpà,” “ìgbésí ayé oníwà wọ̀bìà,” “àwọn ẹlẹ́dẹ̀,” “pódi èso kárọ́ọ̀bù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 15:11-16, nwtsty)
Lk 15:17-24—Ó ronú pìwà dà, bàbá rẹ̀ sì gbà á pa dà torí pé ó nífẹ̀ẹ́ ọmọ náà (“sí ọ,” “ọkùnrin tí o háyà,” “fi ẹnu kò ó lẹ́nu lọ́nà jẹ̀lẹ́ńkẹ́,” “pè ní ọmọkùnrin rẹ,” “aṣọ . . . òrùka . . . sálúbàtà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 15:17-24, nwtsty)
Lk 15:25-32—Wọ́n tún ìrònú ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣe
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Lk 14:26—Kí ni ọ̀rọ̀ náà “kórìíra” túmọ̀ sí níbí yìí? (“kórìíra” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 14:26, nwtsty)
Lk 16:10-13—Kí ni Jésù fẹ́ kí àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ mọ̀ nípa “ọrọ̀ àìṣòdodo”? (w17.07 8-9 ¶7-8)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 14:1-14
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Kó o sì pe ẹni náà wá sí ìpàdé.
Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò, kó o sì fún un ní ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 32 ¶14-15
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ọmọ Onínàákúnàá Pa Dà Wálé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ wo fídíò Ọmọ Onínàákúnàá Pa Dà Wálé-Àyọlò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 11 ¶1-9
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 139 àti Àdúrà