ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 September ojú ìwé 2
  • September 3-9

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • September 3-9
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 September ojú ìwé 2

September 3-9

JÒHÁNÙ 1-2

  • Orin 13 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ Tí Jésù Ṣe”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù.]

    • Jo 2:1-3​—Ohun tó lè dójú tini ṣẹlẹ̀ níbí àsè ìgbéyàwó kan (w15 6/15 4 ¶3)

    • Jo 2:4-11​—Ohun tí Jésù ṣe mú kí ìgbàgbọ́ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ túbọ̀ lágbára (jy 41 ¶6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jo 1:1​—Kí nìdí tá a fi gbà pé Jòhánù kò sọ pé ìkan náà ni “Ọ̀rọ̀ náà” àti Ọlọ́run Olódùmarè? (“ọ̀rọ̀ náà,” “pẹ̀lú,” “ọ̀rọ̀ náà sì jẹ́ ọlọ́run kan” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 1:1, nwtsty)

    • Jo 1:29​—Kí nìdí tí Jòhánù Arinibọmi fi pe Jésù ní “Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run”? (“ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 1:29, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 1:​1-18

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 41 ¶10-11

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 38

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 12 ¶9-14

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 121 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́