September Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé September 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ September 3-9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 1-2 Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ Tí Jésù Ṣe September 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 3-4 Jésù Wàásù fún Obìnrin Ará Samáríà Kan MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bá A Ṣe Lè Sọ Ìjíròrò Lásán Di Ìwàásù September 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 5-6 Ní Èrò Tó Tọ́ Bó O Ṣe Ń Tẹ̀lé Jésù MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Wọn Ò Fi Ohunkóhun Ṣòfò September 24-30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 7-8 Jésù Yin Baba Rẹ̀ Lógo MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ní Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀, Kó O Sì Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bí I Ti Jésù