ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 September ojú ìwé 5
  • Wọn Ò Fi Ohunkóhun Ṣòfò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wọn Ò Fi Ohunkóhun Ṣòfò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Túbọ̀ Já Fáfá Lẹ́nu Iṣẹ́ Rẹ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ẹ Jẹ́ Ká Máa Fi Ọgbọ́n Lo Àwọn Ìwé Ìkẹ́kọ̀ọ́ Wa
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2005
  • Báwo Ni Iṣẹ́ Ṣe Ń Lọ Sí Ní Warwick?
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
  • Máa Fi Ìmọrírì Àtọkànwá Hàn fún Àwọn Ìwé Ìkẹ́kọ̀ọ́ Wa
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2002
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 September ojú ìwé 5
Orílé-iṣẹ́ ní Warwick, New York

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Wọn Ò Fi Ohunkóhun Ṣòfò

Lẹ́yìn tí Jésù bọ́ àwọn obìnrin, àwọn ọmọ kéékèèké pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ọkùnrin, ó sọ fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ pé: “Ẹ kó èébù tí ó ṣẹ́ kù jọpọ̀, kí ó má bàa sí ohun tí a fi ṣòfò.” (Jo 6:12) Bí Jésù kò ṣe fi ohunkóhun ṣòfò fi hàn pé ó mọrírì ohun tí Jèhófà pèsè.

Lóde òní, Ìgbìmọ̀ Olùdarí náà ń gbìyànjú láti tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù lórí bí wọ́n ṣe ń fọgbọ́n lo ohun tá a fi ń ṣètìlẹyìn. Bí àpẹẹrẹ, nígbà tá a ń kọ́ orílé-iṣẹ́ wa ní Warwick, New York, àwọn arákùnrin yan àwòrán ilé tó máa jẹ́ ká lè lo owó tá a fi ń ṣètìlẹyìn lọ́nà tó dáa.

KÍ LA LÈ ṢE TÁ Ò FI NÍ MÁA FI NǸKAN ṢÒFÒ . . .

  • Arákùnrin kan ń paná Gbọ̀ngàn Ìjọba

    nígbà tá a bá wà nípàdé?

  • Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ń kọ orúkọ rẹ̀ sínú Bíbélì rẹ̀

    nígbà tá a bá gba ìwé tá a fẹ́ lò fúnra wa? (km 5/09 3 ¶4)

  • Arákùnrin kan ń mú ìwọ̀nba ìwé tó máa lò

    nígbà tá a bá gba ìwé tá a fẹ́ lò ní òde-ẹ̀rí? (mwb17.02 “Máa Fọgbọ́n Lo Àwọn Ìtẹ̀jáde Wa” ¶1)

  • Arábìnrin kan fẹ́ mọ̀ bóyá obìnrin kan nífẹ̀ẹ́ sí ìwé wa kó tó fún un

    nígbà tá a bá wà lóde ẹ̀rí? (mwb17.02 “Máa Fọgbọ́n Lo Àwọn Ìtẹ̀jáde Wa” ¶2 àti àpótí)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́