ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 September ojú ìwé 3
  • September 10-16

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • September 10-16
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 September ojú ìwé 3

September 10-16

JÒHÁNÙ 3-4

  • Orin 57 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jésù Wàásù fún Obìnrin Ará Samáríà Kan”: (10 min.)

    • Jo 4:6, 7​—Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti rẹ Jésù, síbẹ̀ ó wàásù fún obìnrin ará Samáríà kan (“tí ó ti rẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 4:6, nwtsty)

    • Jo 4:21-24​—Bí Jésù ṣe wàásù fún obìnrin náà mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn gbọ́ nípa Mèsáyà

    • Jo 4:39-41​—Ọ̀pọ̀ àwọn ará Samáríà ló gba Jésù gbọ́, torí pé ó sapá láti bá obìnrin yẹn sọ̀rọ̀

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jo 3:29​—Kí ni ẹsẹ Bíbélì yìí túmọ̀ sí? (“ọ̀rẹ́ ọkọ ìyàwó” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 3:29, nwtsty)

    • Jo 4:10​—Kí ló ṣeé ṣe kí obìnrin ará Samáríà yẹn máa rò nígbà tí Jésù sọ̀rọ̀ nípa “omi ààyè,” àmọ́ kí ni Jésù ń tọ́ka sí? (“omi ààyè” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 4:10, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 4:​1-15

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.2 9 ¶1-4​—Àkòrí: Ìtumọ̀ Ọ̀rọ̀ Inú Jòhánù 4:23.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 77

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Bá A Ṣe Lè Sọ Ìjíròrò Lásán Di Ìwàásù”: (15 min.) Ìjíròrò. Ní ìparí iṣẹ́ rẹ, gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò kan tó máa yọrí sí ìwàásù láàárín lọ́sẹ̀ yìí. Ní ìpàdé àárín ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀, àwọn akéde máa láǹfààní láti sọ ìrírí tí wọ́n ní.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 12 ¶15-22 àti àpótí Ṣé Ọ̀rọ̀ Ẹnu Mi Ń Gbéni Ró?

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 35 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́