ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 September ojú ìwé 4
  • September 17-23

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • September 17-23
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 September ojú ìwé 4

September 17-23

JÒHÁNÙ 5-6

  • Orin 2 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ní Èrò Tó Tọ́ Bó O Ṣe Ń Tẹ̀ Lé Jésù”: (10 min.)

    • Jo 6:9-11​—Jésù bọ́ ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́nà ìyanu (“àwọn ènìyàn náà rọ̀gbọ̀kú, nǹkan bí ẹgbẹ̀rún márùn-ún ní iye” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 6:10, nwtsty)

    • Jo 6:14, 24​—Àwọn èèyàn gbà pé Jésù ni Mèsáyà, wọ́n sì wá a wá lọ́jọ́ kejì (“Wòlíì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 6:14, nwtsty)

    • Jo 6:25-27, 54, 60, 66-69​—Torí pé èrò tí kò tọ́ ló mú káwọn èèyàn náà máa tẹ̀ lé Jésù àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn, wọ́n fi Jésù sílẹ̀ torí ọ̀rọ̀ tó sọ kò yé wọn (“oúnjẹ tí ń ṣègbé . . . oúnjẹ tí ó wà títí ìyè àìnípẹ̀kun” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 6:27, nwtsty; “fi ẹran ara mi ṣe oúnjẹ jẹ, tí ó sì ń mu ẹ̀jẹ̀ mi” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 6:54, nwtsty; w05 9/1 21 ¶13-14)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jo 6:44​—Báwo ni Baba ṣe ń fa àwọn èèyàn sọ́dọ̀ ara rẹ̀? (“fà á” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 6:44, nwtsty)

    • Jo 6:64​—Ọ̀nà wo ni Jésù gbà mọ̀ “láti ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀” pé Júdásì ló máa da òun? (“Jésù mọ . . . ẹni tí yóò dà á” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 6:64, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 6:​41-59

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ẹni náà sọ pé Kristẹni lòun.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 31

  • Báwo Ló Ṣe Lọ Sí?: (5 min.) Ìjíròrò. Ní kí àwọn ará sọ ìrírí tí wọ́n ní nígbà tí wọ́n gbìyànjú láti bá ẹni tí wọn ò mọ̀ rí sọ̀rọ̀, tó sì wá yọrí sí ìwàásù.

  • “Wọn Ò Fi Ohunkóhun Ṣòfò”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ilé Tá A Kọ́ Lọ́nà Tí Kò Pa Àyíká Lára Fògo fún Jèhófà​—Àyọlò.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 13 ¶1-4, àpótí Ṣó Yẹ Kí N Lọ́wọ́ Sí Ayẹyẹ Yẹn? àti Bá A Ṣe Lè Ṣèpinnu Tó Mọ́gbọ́n Dán [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ ka àpótí tàbí àfikún]

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 89 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́