ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 October ojú ìwé 7
  • October 29–November 4

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 29–November 4
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 October ojú ìwé 7

October 29–November 4

JÒHÁNÙ 18-19

  • Orin 54 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jésù Jẹ́rìí sí Òtítọ́”: (10 min.)

    • Jo 18:36​—Orí Ìjọba Mèsáyà ni òtítọ́ dá lé

    • Jo 18:37​—Jésù jẹ́rìí sí òtítọ́ nípa àwọn ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún aráyé (“jẹ́rìí sí,” “òtítọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 18:37, nwtsty)

    • Jo 18:38a​—Ó hàn pé Pílátù ò gbà pé nǹkan kan wà tó ń jẹ́ òtítọ́ (“Kí ni òtítọ́?” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 18:38a, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jo 19:30​—Kí ló túmọ̀ sí pé Jésù “jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ lọ́wọ́”? (“ó jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ lọ́wọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 19:30, nwtsty)

    • Jo 19:31​—Ẹ̀rí wo ló fi hàn pé Nísàn 14, ọdún 33 Sànmánì Kristẹni ni Jésù kú? (“ọjọ́ Sábáàtì yẹn jẹ́ ọjọ́ ńlá” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Joh 19:31, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 18:1-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkànnì jw.org han onílé.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Bíbélì àti ìbéèrè fún ìgbà míì.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 14 ¶6-7

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 46

  • “Ìfẹ́ Ni A Fi Ń Dá Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Mọ̀​—Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Òtítọ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà “Ẹ Ní Ìfẹ́ Láàárín Ara Yín”​—Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Òtítọ́, Kì Í Ṣe Lórí Àìṣòdodo. Bí àkókò bá ṣe wà sí, sọ̀rọ̀ lórí àpótí náà “Ṣàṣàrò Lórí Àpẹẹrẹ Inú Bíbélì.”

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 15 ¶1-9

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 32 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́