ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 October ojú ìwé 7
  • Jésù Jẹ́rìí sí Òtítọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Jẹ́rìí sí Òtítọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Kristẹni Ń jọ́sìn Ní Ẹ̀mí Àti Òtítọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Ìtọ́ni Jésù Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Láti Jẹ́rìí Kúnnákúnná
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Èéṣe Tí A Fi Ń Wá Òtítọ́ Kiri?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
  • “Títí Dé Ibi Tó Jìnnà Jù Lọ ní Ayé”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 October ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 18-19

Jésù Jẹ́rìí sí Òtítọ́

18:​36-38a

Jésù jẹ́rìí sí òtítọ́ nípa àwọn nǹkan tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún aráyé

  • NÍNÚ Ọ̀RỌ̀: Ó fi ìtara wàásù òtítọ́ nípa Ìjọba Ọlọ́run[1]

  • NÍNÚ ÌṢE: Ọ̀nà tó gbà gbé ìgbésí ayé rẹ̀ mú kí àwọn àsọtẹ́lẹ̀ tí Ọlọ́run sọ nípa rẹ̀ já sí òtítọ́

Àwa náà ń jẹ́rìí sí òtítọ́ torí pé ọmọlẹ́yìn Jésù la jẹ́

  • NÍNÚ Ọ̀RỌ̀: Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn ń pẹ̀gàn wa, síbẹ̀ à ń fi ìtara wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run tó ti ń ṣàkóso báyìí, èyí tí Kristi jẹ́ Ọba rẹ̀[2]

  • NÍNÚ ÌṢE: Bí a ò ṣe ń dá sọ̀rọ̀ òṣèlú àti ogun, tá a sì ń hùwà tínú Ọlọ́run dùn sí fi hàn pé ìjọba Jésù là ń tì lẹ́yìn

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ó hàn sáwọn tó wà láyìíká mi pé bí mo ṣe máa jẹ́rìí sí òtítọ́ ló jẹ mí lógún?’

Àwọn arábìnrin fi fídíò han obìnrin kan; arákùnrin kan ń wàásù fún ẹnì kan; òbí àti àwọn ọmọ ń ṣe ìjọsìn ìdílé; arábìnrin kan ń wàásù fún ẹni tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́