November 5-11
Jòhánù 20-21
Orin 35 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ìwọ Ha Nífẹ̀ẹ́ Mi Ju Ìwọ̀nyí Lọ Bí?”: (10 min.)
Jo 21:1-3—Lẹ́yìn ikú Jésù, Pétérù àti àwọn ọmọlẹ́yìn míì pa dà sídìí iṣẹ́ apẹja
Jo 21:4-14—Lẹ́yìn tí Jésù jíǹde, ó fara han Pétérù àti àwọn ọmọlẹ́yìn míì
Jo 21:15-19—Jésù ran Pétérù lọ́wọ́ láti mọ ohun tó fi sí ipò àkọ́kọ́ nígbèésí ayé rẹ̀ (“Jésù wí fún Símónì Pétérù pé,” “ìwọ ha nífẹ̀ẹ́ mi ju ìwọ̀nyí lọ bí?”, “ní ìgbà kẹta” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 21:15, 17, nwtsty)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Jo 20:17—Kí ni ìtúmọ̀ ọ̀rọ̀ tí Jésù sọ fún Màríà Magidalénì? (“Dẹ́kun dídìrọ̀ mọ́ mi” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 20:17, nwtsty)
Jo 20:28—Kí nìdí tí Tọ́másì fi pe Jésù ní “Olúwa mi àti Ọlọ́run mi”? (“Olúwa mi àti Ọlọ́run mi!” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 20:28, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 20:1-18
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 73 ¶21-22. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 15 ¶10-17 àti àpótí Ṣé Kí N Ṣiṣẹ́ Yìí?
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 45 àti Àdúrà