November Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé November 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ November 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 20-21 “Ìwọ Ha Nífẹ̀ẹ́ Mi Ju Ìwọ̀nyí Lọ Bí?” November 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 1-3 Ọlọ́run Tú Ẹ̀mí Mímọ́ Sórí Ìjọ Kristẹni MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ Fọwọ́ Sowọ́ Pọ̀ Láti Wàásù Láwọn Ìpínlẹ̀ Ìwàásù Tí Wọ́n Ti Ń Sọ Onírúurú Èdè November 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 4-5 Wọ́n Ń Fi Àìṣojo Sọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àǹfààní Tí Àtẹ Tó Ṣeé Tì Kiri Ti Ṣe Wá Kárí Ayé November 26–December 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | IṢE 6-8 Ìjọ Kristẹni Tuntun Kojú Ìṣòro MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Ẹ̀bùn Tá A Mú Dání Wá fún Jèhófà”