ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 November ojú ìwé 6
  • November 26–December 2

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 26–December 2
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 November ojú ìwé 6

November 26–December 2

Ìṣe 6-8

  • Orin 124 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ìjọ Kristẹni Tuntun Kojú Ìṣòro”: (10 min.)

    • Iṣe 6:1​—Ó fẹ́ jọ pé àwọn kan nínú ìjọ ń gbójú fo àwọn opó tó ń sọ èdè Gíríìkì nítorí ẹ̀yà wọn (bt 41 ¶17)

    • Iṣe 6:​2-7​—Àwọn àpọ́sítélì bójú tó ìṣòro náà (bt 42 ¶18)

    • Iṣe 7:58–8:1​—Wọ́n ṣe inúnibíni ńláǹlà sí ìjọ

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 6:15​—Kí ló túmọ̀ sí nígbà tí Bíbélì sọ pé ojú Sítéfánù rí “bí ojú áńgẹ́lì”? (bt 45 ¶2)

    • Iṣe 8:​26-30​—Lóde òní, ọ̀nà wo ni àwọn Kristẹni gbà láǹfààní láti ṣe irú iṣẹ́ tí Fílípì ṣe? (bt 58 ¶16)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 6:​1-15

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Kó o sì pe ẹni náà wá sí ìpàdé.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ ìwé mímọ́ tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 33 ¶16-17

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 109

  • “Ẹ̀bùn Tá A Mú Dání Wá fún Jèhófà”: (15 min.) Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Ẹ kọ́kọ́ wo fídíò náà ‘Ẹ̀bùn Tá A Mú Dání Wá fún Jèhófà’. Ka lẹ́tà tó wá látọ̀dọ̀ ẹ̀ka ọ́fíìsì tí wọ́n fi ń dúpẹ́ fún àwọn ọrẹ tí wọ́n rí gbà ní ọdún iṣẹ́ ìsìn tó kọjá. Sọ àwọn àǹfààní tá a máa rí bá a ṣe ń ṣe ọrẹ. Sọ àwọn ohun tí ìjọ máa ń náwó lé lóṣooṣù. Jíròrò bá a ṣe lè ṣe ọrẹ àti ohun tí wọ́n ń lo àwọn ọrẹ náà fún. Gbóríyìn fún ìjọ fún àwọn ọrẹ tí wọ́n fi ń ṣe ìtìlẹ́yìn.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 16 ¶9-14, àti àpótí Ṣọ́ra Fún Ọgbọ́n Ẹ̀wẹ́ Sátánì!

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 67 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́