ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 November ojú ìwé 4
  • November 19-25

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 19-25
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 November ojú ìwé 4

November 19-25

Ìṣe 4-5

  • Orin 73 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Wọ́n Ń Fi Àìṣojo Sọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”: (10 min.)

    • Iṣe 4:​5-13​—Bó tilẹ̀ jẹ́ pé “ènìyàn tí kò mọ̀wé àti gbáàtúù” ni Pétérù àti Jòhánù, síbẹ̀ wọ́n gbèjà ìgbàgbọ́ wọn níwájú àwọn olùṣàkóso àti àwọn akọ̀wé òfin (w08 9/1 15, àpótí; w08 5/15 30 ¶6)

    • Iṣe 4:​18-20​—Wọ́n halẹ̀ mọ́ Pétérù àti Jòhánù àmọ́ wọn ò dẹ́kun wíwàásù

    • Iṣe 4:​23-31​—Ẹ̀mí mímọ́ Jèhófà ni àwọn Kristẹni ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní gbára lé kí wọ́n bàa lè ní ìgboyà (it-1 128 ¶3)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 4:11​—Ọ̀nà wo ni Jésù gbà jẹ́ “olórí igun ilé”? (it-1 514 ¶4)

    • Iṣe 5:1​—Kí nìdí tí Ananíà àti Sáfírà fi tà lára àwọn ohun ìní wọn? (w13 3/1 15 ¶4)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 5:​27-42

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn ní ìpínlẹ̀ yín sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ pé òun kì í ṣe Kristẹni.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 82

  • “Àǹfààní Tí Àtẹ Tó Ṣeé Tì Kiri Ti Ṣe Wá Kárí Ayé”: (15 min.) Ìjíròrò. Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Ẹ wo fídíò náà. Tẹ́ ẹ bá ń fi àtẹ ìwé tàbí èyí tó ṣeé tì kiri wàásù nínú ìjọ yín, fi han àwọn ará. Sọ ètò tí ìjọ yín ti ṣe. Tí àkókò bá wà, sọ ìrírí kan tẹ́ ẹ ti ní níbi àtẹ ìwé náà tàbí kẹ́ ẹ ṣe àṣefihàn rẹ̀. Sọ bí àwọn ará ṣe lè lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ yìí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 16 ¶1-8

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 64 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́