ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 December ojú ìwé 2
  • December 3-9

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 3-9
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 December ojú ìwé 2

December 3-9

ÌṢE 9-11

  • Orin 115 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹni Tó Ń Ṣe Inúnibíni Di Ẹni Tó Ń Fìtara Wàásù”: (10 min.)

    • Iṣe 9:1, 2​—Sọ́ọ̀lù ṣe inúnibíni tó le gan-an sáwọn ọmọlẹ́yìn Jésù (bt 60 ¶1-2)

    • Iṣe 9:15, 16​—Jésù yan Sọ́ọ̀lù láti máa sọ ìhìn rere nípa òun (w16.06 7 ¶4)

    • Iṣe 9:20-22​—Sọ́ọ̀lù di ẹni tó ń fi ìtara wàásù nípa Jésù (bt 64 ¶15)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 9:4​—Kí nìdí tí Jésù fi bi Sọ́ọ̀lù pé: “Èé ṣe tí ìwọ fi ń ṣe inúnibíni sí mi?” (bt 60-61 ¶5-6)

    • Iṣe 10:6​—Kí nìdí tó fi yani lẹ́nu pé Pétérù ń sùn sọ́dọ̀ ẹni tó jẹ́ oníṣẹ́ awọ? (“Símónì kan, oníṣẹ́ awọ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 10:6, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 9:​10-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 6

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 58

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 16 ¶15-22 àti àpótí Ṣé Ìbẹ́mìílò Ni Lóòótọ́ [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ ka àpótí tàbí àfikún]

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 59 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́