ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 December ojú ìwé 2
  • Ẹni Tó Ń Ṣe Inúnibíni Di Ẹni Tó Ń Fìtara Wàásù

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹni Tó Ń Ṣe Inúnibíni Di Ẹni Tó Ń Fìtara Wàásù
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Iṣẹ́ Ìwàásù Mú Kí Wọ́n Ṣe Inúnibíni sí Sọ́ọ̀lù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Onínúnibíni Rí Ìmọ́lẹ̀ Ńlá
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Jésù Yan Sọ́ọ̀lù
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Ìjọ “Wọnú Àkókò Àlàáfíà”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 December ojú ìwé 2
Sọ́ọ̀lù ṣubú lulẹ̀ nígbà tí iná tàn sí i lójú láti ọ̀run

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 9-11

Ẹni Tó Ń Ṣe Inúnibíni Di Ẹni Tó Ń Fìtara Wàásù

9:15, 16, 20-22

Sọ́ọ̀lù tètè fi ohun tó ń kọ́ sílò. Kí nìdí tí Sọ́ọ̀lù fi ṣiṣẹ́ lórí ẹ̀kọ́ tó kọ́, tí àwọn mí ì kò sì ṣe bẹ́ẹ̀? Ìdí ni pé ó bẹ̀rù Ọlọ́run ju èèyàn lọ, ó sì mọrírì bí Kristi ṣe fi ojú àánú hàn sí òun. Tó o bá ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì àmọ́ tó ò tí ì ṣèrìbọmi, ṣé wàá ṣe bíi ti Sọ́ọ̀lù, ṣé wàá ṣiṣẹ́ lórí ohun tó ò ń kọ́?

ǸJẸ́ O MỌ̀?

Àwọn ará Róòmù gba àwọn Júù láyè láti máa bójú tó ọ̀rọ̀ ìdájọ́ láàárín ara wọn. Yàtọ̀ síyẹn, Ìgbìmọ̀ Sànhẹ́dírìn àti àlùfáà àgbà ní àṣẹ́ láti pinnu ohun tó tọ́ àti ohun tí kò tọ́ fún àwọn Júù níbi gbogbo. Torí náà, wọ́n láṣẹ láti sọ fún Sọ́ọ̀lù pé kó lọ ti àwọn Júù tó ṣẹ̀ṣẹ̀ di Kristẹni mọ́lé, kódà tí wọ́n bá tiẹ̀ wà níbi tó jìnnà pàápàá, irú bíi Damásíkù.

Àwòrán ilẹ̀ láti Jerúsálẹ́mù sí Damásíkù
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́