ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 December ojú ìwé 3
  • December 10-16

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 10-16
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 December ojú ìwé 3

December 10-16

ÌṢE 12-14

  • Orin 60 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn”: (10 min.)

    • Iṣe 13:2, 3​—Jèhófà yan Bánábà àti Sọ́ọ̀lù fún iṣẹ́ pàtàkì kan (bt 86 ¶4)

    • Iṣe 13:12, 48; 14:1​—Iṣẹ́ àṣekára tí wọ́n ṣe mú èso jáde (bt 95 ¶5)

    • Iṣe 14:21, 22​—Bánábà àti Sọ́ọ̀lù fún àwọn ọmọlẹ́yìn tuntun níṣìírí (w14 9/15 13 ¶4-5)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 12:21-23​—Kí la rí kọ́ látinú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Hẹ́rọ́dù? (w08 5/15 32 ¶7)

    • Iṣe 13:9​—Kí nìdí tí wọ́n tún ń pe Sọ́ọ̀lù ní Pọ́ọ̀lù? (“Sọ́ọ̀lù, ẹni tí ó tún ń jẹ́ Pọ́ọ̀lù” àti “Pọ́ọ̀lù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 13:9, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 12:1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bt 79 ¶8-9​—Àkòrí: Máa Gbàdúrà Fún Àwọn Tá A Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 65

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Ran Àwọn Tó Ní ‘Ìtẹ̀sí-Ọkàn Títọ́’ Lọ́wọ́ Láti Di Ọmọlẹ́yìn”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà Jèhófà Ọlọ́run Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 17 ¶1-10

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 55 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́