ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 February ojú ìwé 5
  • February 18-24

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 18-24
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 February ojú ìwé 5

February 18-24

RÓÒMÙ 7-8

  • Orin 27 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ṣé Ò Ń Fojú Sọ́nà Pẹ̀lú Ìháragàgà?”: (10 min.)

    • Ro 8:19​—A máa tó ṣí “àwọn ọmọ Ọlọ́run” payá (w12 7/15 11 ¶17)

    • Ro 8:20​—“A tẹ ìṣẹ̀dá lórí ba fún ìmúlẹ̀mófo . . . nítorí ìrètí” (w12 3/15 23 ¶11)

    • Ro 8:21​—‘A óò dá ìṣẹ̀dá sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìsọdẹrú fún ìdíbàjẹ́’ (w12 3/15 23 ¶12)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ro 8:6​—Kí ni ìyàtọ̀ tó wà láàárín “gbígbé èrò inú ka ẹran ara” àti “gbígbé èrò inú ka ẹ̀mí”? (w17.06 3)

    • Ro 8:26, 27​—Báwo ni Jèhófà ṣe máa ń dáhùn “àwọn ìkérora tí a kò sọ jáde”? (w09 11/15 7 ¶20)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 7:13-25 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 9)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 139

  • “Máa Fi Ìháragàgà Dúró Dè É Pẹ̀lú Ìfaradà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò A Gbọ́dọ̀ ‘Fi Ìfaradà Sáré’​—Jẹ́ Kó Dá Ọ Lójú Pé Wàá Gba Èrè.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 3 ¶1-6

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 124 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́