February Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé February 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ February 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 1-3 Máa Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Máa Ń Rí Àwọn Ànímọ́ Ọlọ́run Tí A Kò Lè Rí? February 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 4-6 “Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Tirẹ̀ fún Wa” February 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 7-8 Ṣé Ò Ń Fojú Sọ́nà Pẹ̀lú Ìháragàgà? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Fi Ìháragàgà Dúró Dè É Pẹ̀lú Ìfaradà February 25–March 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 9-11 Àpèjúwe Igi Ólífì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Fòpin Sí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Tí Kò Méso Jáde