ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 April ojú ìwé 3
  • Jèhófà Jẹ́ Olóòótọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Jẹ́ Olóòótọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Bí Ẹ̀mí Mímọ́ Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 April ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 10-13

Jèhófà Jẹ́ Olóòótọ́

10:13

Arábìnrin kan ń ronú nípa àdánwò kan, ó gbàdúrà nípa rẹ̀, ó sì lọ sóde ẹ̀rí pẹ̀lú arábìnrin mí ì

Jèhófà lè yàn láti mú àdánwò kan kúrò; àmọ́, ó sábà máa ń “ṣe ọ̀nà àbáyọ” ní ti pé ó máa pèsè àwọn nǹkan tá a nílò ká lè fara dà á.

  • Jèhófà máa ń lo Ọ̀rọ̀ rẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ àtàwọn ìtẹ̀jáde tó ń pèsè láti mú kí ọkàn wa balẹ̀, kára sì tù wá.​—Mt 24:45; Jo 14:​16, àlàyé ìsàlẹ̀; Ro 15:4

  • Ó lè fi ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ darí wa, èyí tó máa jẹ́ ká rántí àwọn àkọsílẹ̀ kan nínú Bíbélì tàbí àwọn ìlànà kan táá jẹ́ ká lè ṣe ìpinnu tó bọ́gbọ́n mu.​—Jo 14:26

  • Ó lè lo àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ láti ràn wá lọ́wọ́.​—Heb 1:14

  • Ó lè lo àwọn ará wa láti ràn wá lọ́wọ́.​—Kol 4:11

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́