May 6-12
2 KỌ́RÍŃTÌ 4-6
Orin 128 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“A Kò Juwọ́ Sílẹ̀”: (10 min.)
2Kọ 4:16—Jèhófà ń sọ wá di ọ̀tun “láti ọjọ́ dé ọjọ́” (w04 8/15 25 ¶16-17)
2Kọ 4:17—Ìṣòro tó ń dé bá wa báyìí jẹ́ “fún ìgbà díẹ̀, kò sì lágbára” (it-1 724-725)
2Kọ 4:18—Àwọn ìbùkún tá a máa gbádùn nínú Ìjọba Ọlọ́run ló yẹ ká gbájú mọ́
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
2Kọ 4:7—Kí ni “ìṣúra yìí nínú àwọn ohun èlò tí a fi amọ̀ ṣe”? (w12 2/1 28)
2Kọ 6:13—Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé ìmọ̀ràn tó ní ká “ṣí ọkàn [wa] sílẹ̀ pátápátá”? (w09 11/15 21 ¶7)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Kọ 4:1-15 (th ẹ̀kọ́ 12)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Kàwé Lọ́nà Tó Tọ́, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 5 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w04 7/1 30-31—Àkòrí: Ṣé Ó Yẹ Kí Kristẹni Tó Ti Ṣe Ìrìbọmi Máa Fẹ́ Akéde Tí Kò Tíì Ṣèrìbọmi Sọ́nà? (th ẹ̀kọ́ 7)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Mò Ń Ṣe Gbogbo Ohun Tí Mo Lè Ṣe: (8 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará ní àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni Arákùnrin Foster ṣe ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe nínú iṣẹ́ ìsìn Jèhófà nígbà tó ṣì jẹ́ ọ̀dọ́ tó sì lókun? Báwo ni nǹkan ṣe yí pa dà fún un? Báwo ló ṣe ń ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe nínú ìjọsìn Jèhófà nígbà tí nǹkan yí pa dà fún un? Ẹ̀kọ́ wo lo ti rí kọ́ nínú ìrírí arákùnrin yìí?
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (7 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 5 ¶21-22 àti àfikún Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa—Ìrántí Ikú Kristi Tá A Ń Ṣe Láti Bọlá fún Ọlọ́run
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 65 àti Àdúrà