May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé May 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ May 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 KỌ́RÍŃTÌ 4-6 “A Kò Juwọ́ Sílẹ̀” May 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 KỌ́RÍŃTÌ 7-10 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìrànwọ́ Tá À Ń Ṣe MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bí Àwọn Ará Wa Ní Caribbean Ṣe Jàǹfààní Nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìrànwọ́ Tá À Ń Ṣe May 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 KỌ́RÍŃTÌ 11-13 Ẹ̀gún Nínú Ara Pọ́ọ̀lù MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI O Lè Ṣàṣeyọrí Láìka Ti “Ẹ̀gún” Tó Wà Nínú Ara Rẹ Sí! May 27–June 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | GÁLÁTÍÀ 1-3 “Mo Ta Kò Ó Lójúkojú” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bí Gbogbo Wa Ṣe Lè Máa Bójú Tó Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa