June 10-16
ÉFÉSÙ 1-3
Orin 112 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Iṣẹ́ Àbójútó Jèhófà àti Ohun Tó Wà Fún”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Éfésù.]
Ef 1:8, 9—Ìjọba Mèsáyà wà lára “àṣírí mímọ́” náà (it-2 837 ¶4)
Ef 1:10—Jèhófà ń mú kí gbogbo ẹ̀dá rẹ̀ olóye wà ní ìṣọ̀kan (w12 7/15 27-28 ¶3-4)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ef 3:13—Ọ̀nà wo ni àwọn ìpọ́njú Pọ́ọ̀lù gbà “yọrí sí ògo” fún àwọn Kristẹni tó wà ní Éfésù? (w13 2/15 28 ¶15)
Ef 3:19—Kí ló túmọ̀ sí láti “mọ ìfẹ́ Kristi”? (cl 299 ¶21)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 1:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 1)
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ọ̀kan lára ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ hàn án. (th ẹ̀kọ́ 9)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jẹ́ Kí Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Túbọ̀ Máa Mérè Wá”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ẹ Di “Ọ̀rọ̀ Ìyè Mú Ṣinṣin”—Ẹ Máa Ṣe Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Tó Jíire.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 7 ¶1-8
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 144 àti Àdúrà