June Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé June 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ June 3-9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | GÁLÁTÍÀ 4-6 “Àkàwé” Kan àti Ìtumọ̀ Rẹ̀ June 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÉFÉSÙ 1-3 Iṣẹ́ Àbójútó Jèhófà àti Ohun Tó Wà Fún MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Kí Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Túbọ̀ Máa Mérè Wá June 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÉFÉSÙ 4-6 “Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Kí Ni Jèhófà Máa Fẹ́ Kí N Ṣe? June 24-30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | FÍLÍPÌ 1-4 “Ẹ Má Ṣe Máa Ṣàníyàn Nípa Ohunkóhun” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Fọgbọ́n Yan Eré Ìnàjú Tí Wàá Máa Ṣe