ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 June ojú ìwé 4
  • June 17-23

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 17-23
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 June ojú ìwé 4

June 17-23

ÉFÉSÙ 4-6

  • Orin 71 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”: (10 min.)

    • Ef 6:​11-13​—A nílò ààbò kúrò lọ́wọ́ Sátánì àtàwọn ẹ̀mí èṣù rẹ̀ (w18.05 27 ¶1)

    • Ef 6:​14, 15​—Fi òtítọ́, òdodo àti ìhìn rere àlàáfíà dáàbò bo ara rẹ (w18.05 28-29 ¶4, 7, 10)

    • Ef 6:​16, 17​—Fi ìgbàgbọ́, ìrètí ìgbàlà àti Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dáàbò bo ara rẹ (w18.05 29-31 ¶13, 16, 20)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ef 4:30​—Báwo lẹnì kan ṣe lè kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run? (it-1 1128 ¶3)

    • Ef 5:5​—Kí nìdí tá a fi lè sọ pé abọ̀rìṣà ni ẹni tó bá jẹ́ olójúkòkòrò? (it-1 1006 ¶2)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 4:​17-32 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 8)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 135

  • “Kí Ni Jèhófà Máa Fẹ́ Kí N Ṣe?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ẹ Máa Fi Òye Mọ Ohun Tí Ìfẹ́ Jèhófà Jẹ́ (Le 19:18).

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 7 ¶9-15

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 34 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́