ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 June ojú ìwé 6
  • June 24-30

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 24-30
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 June ojú ìwé 6

June 24-30

FÍLÍPÌ 1-4

  • Orin 33 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Má Ṣe Máa Ṣàníyàn Nípa Ohunkóhun”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Fílípì.]

    • Flp 4:6​—Àdúrà lòògùn àníyàn (w17.08 10 ¶10)

    • Flp 4:7​—Jẹ́ kí “àlàáfíà Ọlọ́run” máa ṣọ́ ẹ (w17.08 10 ¶7; 12 ¶16)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Flp 2:17​—Báwo la ṣe tú àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù “jáde bí ọrẹ ohun mímu”? (it-2 528 ¶5)

    • Flp 3:11​—Kí ni “àjíǹde àkọ́kọ́”? (w07 1/1 26-27 ¶5)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Flp 4:​10-23 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 6 ¶3-4 (th ẹ̀kọ́ 8)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 45

  • Ṣé Fóònù tàbí Tablet Ò Tíì Di Bárakú fún Ẹ?: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Kẹ́ ẹ sì dáhùn àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni àwọn ẹ̀rọ ìgbàlódé wúlò fún? Jàǹbá wo ló lè ṣe fún wa tá a bá jẹ́ kó di bárakú fún wa? Báwo lo ṣe lè mọ̀ tí wọ́n bá ti ń di bárakú fún ẹ? Àwọn nǹkan wo lo lè ṣe láti lè rí i dájú pé o “wádìí dájú àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù”? (Flp 1:10)

  • “Fọgbọ́n Yan Eré Ìnàjú Tí Wàá Máa Ṣe”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Eré Ìnàjú Wo Ló Yẹ Kí N Yàn Láàyò?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 7 ¶16-20 àti àfikún Kí Ni Ṣìọ́ọ̀lù àti Hédíìsì?

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 76 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́