July 15-21
2 TẸSALÓNÍKÀ 1-3
Orin 67 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“A Ó Fi Arúfin Náà Hàn”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Tẹsalóníkà Kejì.]
2Tẹ 2:6-8—A máa fi “arúfin náà,” hàn (it-1 972-973)
2Tẹ 2:9-12—Àwọn tí “arúfin náà” ti ṣì lọ́nà la máa dá lẹ́jọ́ (it-2 245 ¶7)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
2Tẹ 1:7, 8—Kí ló túmọ̀ sí nígbà tí Bíbélì sọ pé ìfihàn Jésù pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ máa jẹ́ “nínú iná tó ń jó fòfò”? (it-1 834 ¶5)
2Tẹ 2:2—Kí ni Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ̀rọ̀ nípa “ọ̀rọ̀ onímìísí”? (it-1 1206 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Tẹ 1:1-12 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni han onílé. (th ẹ̀kọ́ 12)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ṣé Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ Ṣì Máa Ń Fún Ẹ Láyọ̀?: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Koná Mọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ—Lọ́nà Wo?.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 8 ¶8-15
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 111 àti Àdúrà