July Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé July 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ July 1-7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | KÓLÓSÈ 1-4 Ẹ Bọ́ Ìwà Àtijọ́ Sílẹ̀, Kí Ẹ sì Fi Ìwà Tuntun Wọ Ara Yín Láṣọ July 8-14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 TẸSALÓNÍKÀ 1-5 “Ẹ Máa Fún Ara Yín Níṣìírí, Kí Ẹ sì Máa Gbé Ara Yín Ró” July 15-21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 TẸSALÓNÍKÀ 1-3 A Ó Fi Arúfin Náà Hàn July 22-28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 TÍMÓTÌ 1-3 Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀kọ́ Wo Lo Rí Kọ́ Lára Wọn? July 29–August 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 TÍMÓTÌ 4-6 Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Ọrọ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Eré Ìdárayá