August 19-25
HÉBÉRÙ 1-3
Orin 35 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hébérù.]
Heb 1:8—Jésù ń fi “ọ̀pá àṣẹ ìdúróṣinṣin” ṣàkóso (w14 2/15 5 ¶8)
Heb 1:9—Jésù nífẹ̀ẹ́ òdodo, ó sì kórìíra ìwà tí kò bófin mu (w14 2/15 4-5 ¶7)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Heb 1:3—Ṣé àtìbẹ̀rẹ̀ ni Jésù ti máa ń gbé ògo Bàbá rẹ̀ yọ lọ́nà tó ṣe rẹ́gí? (it-1 1185 ¶1)
Heb 1:10-12—Kí nìdí tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù fi lo ọ̀rọ̀ inú Sáàmù 102:25-27 fún Jésù Kristi? (it-1 1063 ¶7)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Heb 1:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fún onílé ní ìwé ìkésíni sí ìpàdé, lẹ́yìn náà ṣe bíi pé o fi fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? han onílé (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 9 ¶10-15
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 101 àti Àdúrà