August Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé August 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ August 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 TÍMÓTÌ 1-4 “Ọlọ́run Kò Fún Wa Ní Ẹ̀mí Ojo” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Kẹ́gbẹ́ Pẹ̀lú Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà August 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | TÍTÙ 1–FÍLÉMÓNÌ “Ẹ Yan Àwọn Alàgbà” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ “Ní Ìtara fún Iṣẹ́ Rere” August 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 1-3 Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu August 26–September 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 4-6 Sa Gbogbo Ipá Rẹ Kó O Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Iṣẹ́ Rere Tá Ò Ní Gbàgbé