October 28–November 3
2 PÉTÉRÙ 1-3
Orin 114 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn Dáadáa”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Pétérù Kejì.]
2Pe 3:9, 10—Ọjọ́ Jèhófà máa dé lásìkò tó yẹ (w06 12/15 27 ¶11)
2Pe 3:11, 12—Ó yẹ ká ronú nípa irú ẹni tó yẹ ká jẹ́ (w06 12/15 19 ¶18)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
2Pe 1:19—Ta ni “ìràwọ̀ ojúmọ́,” ìgbà wo ló yọ, báwo la sì ṣe mọ̀ pé ìràwọ̀ ojúmọ́ ti yọ? (w08 11/15 22 ¶2)
2Pe 2:4—Kí ni “Tátárọ́sì,” ìgbà wo sì ni Ọlọ́run ju àwọn áńgẹ́lì tó ṣọ̀tẹ̀ síbẹ̀? (w08 11/15 22 ¶3)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Pe 1:1-15 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 7)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 145 ¶3-4 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Báwo Lo Ṣe Mọyì Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Tó?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Wọ́n Mọyì Bíbélì—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 12 ¶1-9
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 49 àti Àdúrà