ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 2
  • November 4-10

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 4-10
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 2

November 4-10

1 JÒHÁNÙ 1-5

  • Orin 122 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù Kìíní.]

    • 1Jo 2:​15, 16​—‘Gbogbo ohun tó wà nínú ayé wá látọ̀dọ̀ ayé,’ kì í ṣe látọ̀dọ̀ Baba (w05 1/1 10 ¶13)

    • 1Jo 2:17​—Ayé àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀ ń kọjá lọ (w13 8/15 27 ¶18)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • 1Jo 2:​7, 8​—Báwo ni àṣẹ tí Jòhánù tọ́ka sí ṣe jẹ́ àṣẹ àtijọ́, tó sì tún jẹ́ tuntun? (w13 9/15 10 ¶14)

    • 1Jo 5:​16, 17​—Kí ni ‘ẹ̀ṣẹ̀ tó yẹ fún ikú’? (it-1 862 ¶5)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Jo 1:1–2:6 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ìtara, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 11 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w04 10/1 29​—Àkòrí: Bó ṣe wà nínú 1 Jòhánù 4:​18, kí ni Jòhánù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé “ìfẹ́ tó pé máa ń lé ìbẹ̀rù jáde”? (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 132

  • “Yẹra fún Ẹ̀mí Ayé Tó O Bá Ń Ṣètò Ìgbéyàwó”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ìgbéyàwó Tó Ní Ọlá Lójú Jèhófà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 12 ¶10-16

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 118 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́