November Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé November 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ November 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 JÒHÁNÙ 1-5 Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Yẹra fún Ẹ̀mí Ayé Tó O Bá Ń Ṣètò Ìgbéyàwó November 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 JÒHÁNÙ 1-13; 3 JÒHÁNÙ 1-14–JÚÙDÙ 1-25 A Gbọ́dọ̀ Jà Fitafita Ká Lè Dúró Nínú Òtítọ́ November 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 1-3 “Mo Mọ Àwọn Iṣẹ́ Rẹ” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Mọ Ohun Tá A Nílò November 25–December 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 4-6 Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Tó Ń Gẹṣin Lọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ẹni Tó Ń Fúnni Pẹ̀lú Ìdùnnú