ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 4
  • November 11-17

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 11-17
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 4

November 11-17

2 JÒHÁNÙ 1-13; 3 JÒHÁNÙ 1-14–JÚÙDÙ 1-25

  • Orin 128 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “A Gbọ́dọ̀ Jà Fitafita Ká Lè Dúró Nínú Òtítọ́”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù Kejì.]

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù Kẹta.]

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Júùdù.]

    • Jud 3​—“Ẹ máa jà fitafita torí ìgbàgbọ́” (w04 9/15 11-12 ¶8-9)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jud 4, 12​—Báwo làwọn aláìṣèfẹ́ Ọlọ́run tó yọ́ wọnú ìjọ ṣe dà bí ‘àpáta tó fara pa mọ́ lábẹ́ omi níbi àsè tí a fìfẹ́ pè’? (it-2 279, 816)

    • Jud 14, 15​—Kí nìdí tí Énọ́kù fi sọ àsọtẹ́lẹ̀ yìí bí ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá, báwo sì ni àsọtẹ́lẹ̀ náà ṣe ṣẹ? (wp17.1 12 ¶1, 3)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Jo 1-13 (th ẹ̀kọ́ 12)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 1)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Kó o wá fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG. (th ẹ̀kọ́ 1)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 87

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 12 ¶17-19 àti àpótí Kòrìíra Àwọn Ohun Tí Jèhófà Kórìíra

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 147 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́