ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 6
  • November 25–December 1

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 25–December 1
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 6

November 25–December 1

ÌFIHÀN 4-6

  • Orin 22 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Tó Ń Gẹṣin Lọ”: (10 min.)

    • Ifi 6:2​—Ẹni tó gun ẹṣin funfun náà “jáde lọ, ó ń ṣẹ́gun” (wp17.3 4 ¶3, 5)

    • Ifi 6:​4-6​—Lẹ́yìn náà, ẹni tó gun ẹṣin pupa àti ẹni tó gun ẹṣin dúdú jáde tẹ̀ lé e (wp17.3 5 ¶2, 4-5)

    • Ifi 6:8​—Níkẹyìn, ẹni tó gun ẹṣin ràndánràndán jáde, Isà Òkú sì ń tẹ̀ lé e (wp17.3 5 ¶8-10)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ifi 4:​4, 6​—Kí ni àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún (24) àti ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà ṣàpẹẹrẹ? (re 76-77 ¶8; 80 ¶19)

    • Ifi 5:5​—Kí nìdí tá a fi pe Jésù ní “Kìnnìún ẹ̀yà Júdà”? (cf 36 ¶5-6)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 4:​1-11 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 43 ¶15 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 46

  • “Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ẹni Tó Ń Fúnni Pẹ̀lú Ìdùnnú”: (15 min.) Ìjíròrò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Ẹ kọ́kọ́ wo fídíò náà Àlàyé Lórí Bá A Ṣe Lè Fi Ọrẹ Ṣètìlẹ́yìn Látorí Íńtánẹ́ẹ̀tì. Sọ fáwọn ará pé wọ́n máa rí ìsọfúnni nípa bí wọ́n ṣe lè ṣètọrẹ tí wọ́n bá tẹ ìlujá tá a pè ní Ọrẹ lórí ìkànnì jw.org/yo àti lórí ètò ìṣiṣẹ́ JW Library tàbí kí wọ́n tẹ donate.jw.org síbi tá a máa ń kọ àdírẹ́sì sí lórí íńtánẹ́ẹ̀tì. Ka lẹ́tà tó wá látọ̀dọ̀ ẹ̀ka ọ́fíìsì tí wọ́n fi ń dúpẹ́ àwọn ọrẹ tí wọ́n rí gbà ní ọdún iṣẹ́ ìsìn tó kọjá. Gbóríyìn fáwọn ará fún àwọn ọrẹ tí wọ́n ń ṣe.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 13 ¶1-4

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 43 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́