ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 6
  • Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Tó Ń Gẹṣin Lọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Tó Ń Gẹṣin Lọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Oro Isaaju
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
  • Bí Ọ̀rọ̀ Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Inú Bíbélì Ṣe Kàn Ọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
  • Ta Ni Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Náà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 4-6

Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Tó Ń Gẹṣin Lọ

6:2, 4-6, 8

Jésù ń gun ẹṣin funfun kan, ọfà àti ọrun sì wà ní ọwọ́ rẹ̀; ẹni tó gun ẹṣin aláwọ̀ iná ń tẹ̀ lé e, lẹ́yìn ẹlẹ́ṣin dúdú àti ẹlẹ́ṣin ràndánràndán

Jésù “jáde lọ, ó ń ṣẹ́gun” nígbà tó bá Sátánì àtàwọn ẹ̀mí èṣù rẹ̀ jagun ní ọ̀run, tó sì lé wọn sórí ilẹ̀ ayé. Jésù ń bá ìṣẹ́gun rẹ̀ lọ ní ti pé ó ń ran àwa ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́, ó sì ń dáàbò bò wá láwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí. Ó máa “parí ìṣẹ́gun rẹ̀” nígbà tó bá pa àwọn ẹlẹ́ṣin mẹ́ta yòókù run nígbà ogun Amágẹ́dọ́nì, lẹ́yìn náà ó máa tún gbogbo ohun tí wọ́n ti bà jẹ́ ṣe.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́