ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 2
  • December 2-8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 2-8
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 2

December 2-8

ÌFIHÀN 7-9

  • Orin 63 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Bù Kún Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn Tí Ẹnikẹ́ni Kò Lè Kà”: (10 min.)

    • Ifi 7:9​—“Ogunlọ́gọ̀ èèyàn” náà dúró níwájú ìtẹ́ Jèhófà (it-1 997 ¶1)

    • Ifi 7:14​—Ogunlọ́gọ̀ èèyàn náà máa la “ìpọ́njú ńlá” já (it-2 1127 ¶4)

    • Ifi 7:15-17​—Lọ́jọ́ iwájú, ogunlọ́gọ̀ èèyàn náà máa gbádùn ìbùkún lórí ilẹ̀ ayé (it-1 996-997)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ifi 7:1​—Kí ni “áńgẹ́lì mẹ́rin tí wọ́n dúró lórí igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé” àti “atẹ́gùn mẹ́rin” náà ṣàpẹẹrẹ? (re 113 ¶4)

    • Ifi 9:11​—Ta ni “áńgẹ́lì ọ̀gbun àìnísàlẹ̀” náà? (it-1 12)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 7:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ọ̀yàyà àti Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 12 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.01 25-26 ¶12-16​—Àkòrí: Kí nìdí tí kò fi yẹ ká máa da ara wa láàmú bí àwọn tó ń jẹ búrẹ́dì tí wọ́n sì ń mu wáìnì níbi Ìrántí Ikú Kristi bá ń pọ̀ sí i? (th ẹ̀kọ́ 6)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 93

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 13 ¶5-9

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 27 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́