December Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé December 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ December 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 7-9 Jèhófà Bù Kún Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn Tí Ẹnikẹ́ni Kò Lè Kà December 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 10-12 Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ilẹ̀ ‘Gbé Odò Náà Mì’ December 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 13-16 Má Ṣe Bẹ̀rù Àwọn Ẹranko Abàmì Náà December 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 17-19 Ogun Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun December 30, 2019–January 5, 2020 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 20-22 “Wò Ó! Mò Ń Sọ Ohun Gbogbo di Tuntun” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Yíwọ́ Pa Dà