ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 5
  • Ogun Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ogun Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àlàáfíà Tòótọ́—Láti Orísun Wo?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
  • Nigba Wo ni Alaafia Pipẹtiti Yoo De Niti Gidi?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • Amágẹ́dọ́nì Ogun Ọlọ́run Tó Máa Fòpin Sí Gbogbo Ogun
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Máa Wá Àlàáfíà Tòótọ́, Kí O Sì Máa Lépa Rẹ̀!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 5
Idà gígùn kan jáde látẹnu Jésù bí òun àtàwọn ọmọ ogun ọ̀run ṣe ń gun ẹṣin funfun lọ

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 17-19

Ogun Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun

19:11, 14-16, 19-21

Kí nìdí tí Jèhófà tó jẹ́ “Ọlọ́run ìfẹ́ àti àlàáfíà” fi yan Ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ “Ọmọ Aládé Àlàáfíà” láti ja ogun kan?​—2Kọ 13:11; Ais 9:6.

  • Jèhófà àti Jésù nífẹ̀ẹ́ òdodo, wọ́n sì kórìíra ìwà burúkú

  • Ó dìgbà táwọn èèyàn burúkú ò bá sí mọ́ ká tó lè gbádùn àlàáfíà tòótọ́, kí ìdájọ́ òdodo sì gbilẹ̀

  • Aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa, tó funfun, tó sì mọ́ tónítóní táwọn ọmọ ogun ọ̀run wọ̀ fi hàn pé wọ́n ń “fi òdodo jagun lọ.”

Kí ló yẹ ká ṣe ká lè la ogun pàtàkì yìí já?​—Sef 2:3

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́