ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 5
  • December 23-29

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 23-29
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 5

December 23-29

ÌFIHÀN 17-19

  • Orin 149 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ogun Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun”: (10 min.)

    • Ifi 19:11, 14-16​—Jésù Kristi máa pa àwọn ọ̀tá Ọlọ́run run (w08 4/1 8 ¶3-4; it-1 1146 ¶1)

    • Ifi 19:19, 20​—Ẹranko náà àti wòlíì èké náà máa pa run (re 285 ¶24)

    • Ifi 19:21​—Gbogbo èèyàn tó bá ń ta ko Jèhófà Ọba Aláṣẹ máa pa run (re 286 ¶25)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ifi 17:8​—Ṣàlàyé bí “ẹranko náà ṣe wà tẹ́lẹ̀, àmọ́ tí kò sí, síbẹ̀ tó tún máa wà.” (re 247-248 ¶5-6)

    • Ifi 17:16, 17​—Báwo la ṣe mọ̀ pé òjijì ni ẹ̀sìn èké máa pa run, tí kì í ṣe pé á máa pòórá díẹ̀díẹ̀? (w12 6/15 18 ¶17)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 17:1-11 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 8)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 8 (th ẹ̀kọ́ 13)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 150

  • Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò orin Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà. Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Àwọn ipò wo nígbèésí ayé wa ló ti lè gba pé ká lo ìgboyà? Ìtàn Bíbélì wo ló máa ń fún ẹ nígboyà? Àwọn wo ló wà lẹ́yìn wa? Ní ìparí apá yìí, ní káwọn ará dìde dúró, kẹ́ ẹ sì jọ kọ orin náà “Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà” (èyí tó lọ́rọ̀ orin).

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 14 ¶1-7

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 136 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́