ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 3
  • Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • Àwọn “Egungun Gbígbẹ” Àtàwọn ‘Ẹlẹ́rìí Méjì’—Báwo Ni Wọ́n Ṣe Jọra?
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • A Mú Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì Náà Sọ Jí
    Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
  • Àwọn Ọjọ́ Alásọtẹ́lẹ̀ Danieli àti Ìgbàgbọ́ Wa
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 3
Àwọn ‘ẹlẹ́rìí méjì’ tí ìwé Ìfihàn sọ̀rọ̀ nípa wọn dúró níwájú ọ̀pá fìtílà àti igi ólífì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 10-12

Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè

11:3-11

  • ‘Àwọn ẹlẹ́rìí méjì’: Díẹ̀ lára àwọn ẹni àmì òróró, àwọn yìí ló ń múpò iwájú nígbà tí Ìjọba Ọlọ́run bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso lọ́dún 1914

  • Wọ́n pa wọ́n: Lẹ́yìn tí wọ́n ti wàásù fún ọdún mẹ́ta àtààbọ̀ nínú “aṣọ ọ̀fọ̀,” àwọn alátakò “pa wọ́n” ní ti pé wọ́n jù wọ́n sẹ́wọ̀n, wọ́n sì dáwọ́ iṣẹ́ àwọn ẹlẹ́rìí méjì náà dúró

  • Wọ́n pa dà wà láàyè: Lẹ́yìn tí ọjọ́ mẹ́ta àtààbọ̀ ìṣàpẹẹrẹ náà parí, wọ́n pa dà wà láàyè ní ti pé wọ́n dá wọn sílẹ̀ lẹ́wọ̀n, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í múpò iwájú lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù

Ìwé Ìfihàn 11:1, 2 sọ pé àwọn nǹkan yìí máa wáyé nígbà kan náà tí wọ́n bá wọn tẹ́ńpìlì tẹ̀mí tàbí tí wọ́n bá yẹ̀ ẹ́ wò bó ṣe wà nínú ìwé Málákì 3:1-3. Àkókò tí àwọn àsọtẹ́lẹ̀ ṣẹ: ó bẹ̀rẹ̀ láti ìgbà ìfọ̀mọ́ tẹ́ńpìlì lọ́dún 1914 sí apá ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1919; ọdún mẹ́ta àtààbọ̀ tàbí ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀fà [1,260] ọjọ́, ìyẹ́n bẹ̀rẹ̀ láti nǹkan bí ọdún 1914 sí apá ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1918; ọjọ́ mẹ́ta àtààbọ̀ náà bẹ̀rẹ̀ láti nǹkan bí apá ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1918 sí apá ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1919.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́