February 3-9
JẸ́NẸ́SÍSÌ 12-14
Orin 14 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Májẹ̀mú Kan Tó Kàn Ẹ́”: (10 min.)
Jẹ 12:1, 2—Jèhófà ṣèlérí pé òun máa bù kún Ábúrámù (Ábúráhámù) (it-1 522 ¶4)
Jẹ 12:3—“Gbogbo ìdílé tó wà lórí ilẹ̀ yóò rí ìbùkún gbà nípasẹ̀ [Ábúráhámù]” (w89 7/1 3 ¶4)
Jẹ 13:14-17—Jèhófà fi ilẹ̀ tí òun máa fún àwọn àtọmọdọ́mọ Ábúráhámù hàn án (it-2 213 ¶3)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Jẹ 13:8, 9—Báwo la ṣe lè fara wé Ábúráhámù tá a bá fẹ́ yanjú aáwọ̀? (w16.05 5 ¶12)
Jẹ 14:18-20—Báwo ni Léfì ṣe “san ìdá mẹ́wàá nípasẹ̀ Ábúráhámù”? (Heb 7:4-10; it-2 683 ¶1)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 12:1-20 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Jẹ́ Kí Kókó Ọ̀rọ̀ Fara Hàn Kedere, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 14 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w12 1/1 8—Àkòrí: Kí Ló Mú Kí Sérà Jẹ́ Obìnrin Tó Ṣeyebíye? (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Kí Ló Lè Rí Kọ́ Nínú Àwọn Orin Wa Míì?”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò orin náà Ó Ti Fẹ́rẹ̀ẹ́ Dé Tán.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 15 ¶15-16 àti àfikún Bá A Ṣe Dá “Bábílónì Ńlá” Mọ̀
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 15 àti Àdúrà