February Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé February 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ February 3-9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 12-14 Májẹ̀mú Kan Tó Kàn Ẹ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Kí Ló Lè Rí Kọ́ Nínú Àwọn Orin Wa Míì? February 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 15-17 Kí Nìdí Tí Jèhófà Fi Yí Orúkọ Ábúrámù àti Sáráì Pa Dà? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bí Àwọn Tọkọtaya Ṣe Lè Túbọ̀ Ṣe Ara Wọn Lọ́kan February 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 18-19 “Onídàájọ́ Gbogbo Ayé” Pa Sódómù àti Gòmórà Run MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Látinú Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́? February 24–March 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 20-21 Gbogbo Ìgbà Ni Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ