ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 March ojú ìwé 2
  • March 2-8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 2-8
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 March ojú ìwé 2

March 2-8

JẸ́NẸ́SÍSÌ 22-23

  • Orin 89 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò”: (10 min.)

    • Jẹ 22:1, 2—Ọlọ́run sọ fún Ábúráhámù pé kó fi Ísákì ọmọ ẹ̀ tó nífẹ̀ẹ́ gidigidi rúbọ (w12 1/1 23 ¶4-6)

    • Jẹ 22:​9-12—Jèhófà ò jẹ́ kí Ábúráhámù pa Ísákì

    • Jẹ 22:​15-18—Jèhófà ṣèlérí pé òun máa bù kún Ábúráhámù torí pé ó jẹ́ onígbọràn (w12 10/15 23 ¶6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 22:5—Kí ló mú kí Ábúráhámù sọ fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé òun àti Ísákì máa pa dà wá bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó mọ̀ pé òun máa tó fi Ísákì rúbọ? (w16.02 7 ¶13)

    • Jẹ 22:12—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé kì í ṣe gbogbo ìgbà ni Jèhófà máa ń lo agbára tó ní láti mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú? (it-1 853 ¶5-6)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 22:1-18 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Fi Ìdánilójú Sọ̀rọ̀, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 15 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) it-1 604 ¶5​—Àkòrí: Kí Ló Mú Kí Ọlọ́run Ka Ábúráhámù sí Olódodo kí Jésù Tó San Ìràpadà? (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 4

  • Ìgbọràn Ń Dáàbò Bò Wá: (15 min.) Ẹ wo fídíò náà Ìpàdé Ọdọọdún 2017​—Àwọn Àsọyé àti Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Ọdún 2018​—Àyọlò.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 16 ¶11-15 àti àfikún Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Ṣe Ọdún àti Àwọn Ayẹyẹ Kan?

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 16 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́