March Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé March 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ March 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 22-23 “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò” March 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 24 Bí Ísákì Ṣe Rí Ìyàwó MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Wo Ni Mo Lè Pè? March 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 25-26 Ísọ̀ Ta Ogún Ìbí Rẹ̀ March 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 27-28 Jékọ́bù Gba Ìbùkún Tó Tọ́ Sí I March 30–April 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 29-30 Jékọ́bù Fẹ́ Ìyàwó MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Wàásù fún Àwọn Afọ́jú