ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 March ojú ìwé 4
  • March 16-22

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 16-22
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 March ojú ìwé 4

March 16-22

JẸ́NẸ́SÍSÌ 25-26

  • Orin 18 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ísọ̀ Ta Ogún Ìbí Rẹ̀”: (10 min.)

    • Jẹ 25:27, 28​—Ìbejì ni Ísọ̀ àti Jékọ́bù, àmọ́ ìwà wọn yàtọ̀ síra (it-1 1242)

    • Jẹ 25:29, 30​—Ísọ̀ ò ronú kó tó ṣèpinnu torí pé ó ti rẹ̀ ẹ́, ebi sì ń pa á

    • Jẹ 25:31-34​—Aláìmoore ni Ísọ̀, ó fi ìwàǹwára ta ogún ìbí rẹ̀ fún Jékọ́bù nítorí oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan péré (w19.02 16 ¶11; it-1 835)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 25:31-34​—Kí nìdí tí a ò fi lè lo ẹsẹ Bíbélì yìí láti fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn baba ńlá Mèsáyà gbọ́dọ̀ jẹ́ àkọ́bí? (Heb 12:16; w17.12 15 ¶5-7)

    • Jẹ 26:7​—Kí nìdí tí Ísákì ò fi sọ òkodoro ọ̀rọ̀ nínú ipò tó bá ara rẹ̀ yìí? (it-2 245 ¶6)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 26:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí la lè ṣe tá ò fi ní dójú ti onílé tí kò bá mọ ìdáhùn sí ìbéèrè wa? Báwo ni akéde náà ṣe ṣàlàyé Mátíù 20:28 kó lè wọ onílé lọ́kàn?

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Lẹ́yìn náà fún onílé ní ìwé Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? (th ẹ̀kọ́ 15)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 78

  • Máa Lo Fídíò Tó O Bá Ń Fi Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! Kọ́ni: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Tó Ti Kú? àti Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Gbà Pé Ká Máa Jìyà? Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá wo fídíò kọ̀ọ̀kan tán, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo lo ṣe lè lo fídíò yìí nígbà tó o bá ń fí ìwé Ìròyìn Ayọ̀ kọ́ ẹnì kan lẹ́kọ̀ọ́? (mwb19.03 7) Kí lo kíyè sí nínú fídíò náà tó máa wúlò fún ẹ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? Rán àwọn ara létí pé ẹ̀dà ìwé Ìròyìn Ayọ̀ tó wà lórí ẹ̀rọ̀ ní ìlujá tó máa gbé wọn lọ síbi tí fídíò kọ̀ọ̀kan wà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 17 ¶1-8

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 107 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́