ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 March ojú ìwé 6
  • March 30–April 5

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 30–April 5
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 March ojú ìwé 6

March 30–April 5

JẸ́NẸ́SÍSÌ 29-30

  • Orin 93 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jékọ́bù Fẹ́ Ìyàwó”: (10 min.)

    • Jẹ 29:18-20​—Jékọ́bù gbà láti sin Lábánì fún ọdún méje kó lè fẹ́ Réṣẹ́lì (w03 10/15 29 ¶5)

    • Jẹ 29:21-26​—Lábánì tan Jékọ́bù, ó fún un ní Líà dípò Réṣẹ́lì (w07 10/1 8-9; it-2 341 ¶3)

    • Jẹ 29:27, 28​—Jékọ́bù ṣe ohun tó dáa nínú ipò tí kò rọrùn

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 30:3​—Kí nìdí tí Réṣẹ́lì fi ka ọmọ tí Bílíhà bí fún Jékọ́bù sí ọmọ òun? (it-1 50)

    • Jẹ 30:14, 15​—Kí nìdí tí Réṣẹ́lì fi torí èso máńdírékì yááfì àǹfààní tó ní láti sùn ti ọkọ rẹ̀ kó lè lóyún? (w04 1/15 28 ¶7)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 30:1-21 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Gbéni Ró Kó sì Ṣàǹfààní, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 16 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 59 ¶21-22 (th ẹ̀kọ́ 18)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 57

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Máa Wàásù fún Àwọn Afọ́jú”: (10 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Bi àwọn ará ní ìbéèrè yìí: Kí nìdí tó fí ṣe pàtàkì pé ká ran àwọn afọ́jú lọ́wọ́? Ibo la ti lè rí àwọn afọ́jú? Báwo la ṣe lè bá wọn sọ̀rọ̀ lọ́nà táá fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ wọn? Àwọn nǹkan wo ni ètò Ọlọ́run ti pèsè kí àwọn afọ́jú lè kẹ́kọ̀ọ́ nípa Jèhófà?

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 17 ¶13-17

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 30 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́