ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 April ojú ìwé 5
  • April 20-26

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 20-26
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 April ojú ìwé 5

April 20-26

JẸ́NẸ́SÍSÌ 32-33

  • Orin 21 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ṣé Ò Ń Jìjàkadì Kó O Lè Gba Ìbùkún?”: (10 min.)

    • Jẹ 32:24​—Jékọ́bù bá áńgẹ́lì kan jìjàkadì (w03 8/15 25 ¶3)

    • Jẹ 32:25, 26​—Jékọ́bù ò juwọ́ sílẹ̀ títí tó fi rí ìbùkún gbà (it-2 190)

    • Jẹ 32:27, 28​—Ọlọ́run bù kún Jékọ́bù torí pé ó forí tì í (it-1 1228)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 32:​11, 13-15​—Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jékọ́bù láti máa wá àlàáfíà? (w10 6/15 22 ¶10-11)

    • Jẹ 33:20​—Kí nìdí tí Jékọ́bù fi pe pẹpẹ tó mọ yìí ní “Ọlọ́run, Ọlọ́run Ísírẹ́lì”? (it-1 980)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 32:1-21 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni Ẹ̀bùn ṣe lo àwọn ẹ̀rí tó péye tó sì ń yíni lérò pa dà? Kí ló fi hàn pé Ẹ̀bùn àti Ṣeun ti jọ múra ohun tí wọ́n fẹ́ sọ sílẹ̀?

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 16)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 35

  • “Kí Ló Ṣe Pàtàkì Jù Sí Mi?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Jẹ́ Kí Àwọn Àfojúsùn Tẹ̀mí Wà Lọ́kàn Rẹ Digbí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 18 ¶8-13

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 150 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́