ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 April ojú ìwé 4
  • Jékọ́bù àti Lábánì Dá Májẹ̀mú Àlàáfíà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jékọ́bù àti Lábánì Dá Májẹ̀mú Àlàáfíà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jékọ́bù Mọyì Àwọn Nǹkan Tẹ̀mí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Jékọ́bù Lọ Sí Háránì
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Majẹmu Titun Ti Ọlọrun Ń Súnmọ́ Àṣeparí Rẹ̀
    Àìléwu Kárí-Ayé Labẹ “Ọmọ-Aládé Alaafia”
  • Ẹ̀yin Yóò Di “Ìjọba Àwọn Àlùfáà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 April ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 31

Jékọ́bù àti Lábánì Dá Májẹ̀mú Àlàáfíà

31:44-53

Kí nìdí tí Jékọ́bù àti Lábánì fi fi òkúta ṣe òkìtì?

  • Ó jẹ́ ẹ̀rí fún àwọn tó ń gbabẹ̀ kọjá pé àwọn méjèèjì jọ dá májẹ̀mú àlàáfíà

  • Ó ń rán wọn létí pé Jèhófà ń wò wọ́n kí wọ́n lè mú májẹ̀mú tí wọ́n dá náà ṣẹ

Àwọn àwòrán: 1. Àwọn arábìnrin méjì ń wo ara wọn tìbínú-tìbínú nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba. Lọ́wọ́ ẹ̀yìn, àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin ń kí ara wọn, wọ́n sì ń yọ̀ mọ́ ara wọn. 2. Àwọn arábìnrin méjèèjì jọ jókòó níbi tí wọ́n ti ń gbafẹ́, wọ́n jọ ń mu kọfí, wọ́n sì jọ ń gbádùn ara wọn. Bíbélì àti ẹ̀bùn kékeré kan wà lórí tábìlì.

Lónìí, Jèhófà fẹ́ kí àlàáfíà wà láàárín àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Báwo ni àwọn nǹkan yìí ṣe lè mú kí àlàáfíà jọba nígbà tí èdèkòyédè bá wáyé láàárín wa?

  • Ẹ jọ jókòó sọ ọ́.​—Mt 5:23, 24

  • Ẹ dárí ji ara yín fàlàlà.​—Kol 3:13

  • Ẹ mú sùúrù.​—Ro 12:21

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́