ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 April ojú ìwé 6
  • April 27–May 3

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 27–May 3
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 April ojú ìwé 6

April 27–May 3

JẸ́NẸ́SÍSÌ 34-35

  • Orin 28 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Àkóbá Tí Ẹgbẹ́ Búburú Máa Ń Fà”: (10 min.)

    • Jẹ 34:1​—Léraléra ni Dínà ń lọ sọ́dọ̀ àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ Kénáánì (w97 2/1 30 ¶4)

    • Jẹ 34:2​—Ṣékémù fipá bá Dínà lò pọ̀ (lv 103 ¶14)

    • Jẹ 34:7, 25​—Síméónì àti Léfì pa Ṣékémù àti gbogbo ọkùnrin to wà ní ìlú yẹn (w09 9/1 21 ¶1-2)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 35:8​—Ta ni Dèbórà, kí la sì lè kọ́ lára rẹ̀? (it-1 600 ¶4)

    • Jẹ 35:22-26​—Báwo la ṣe mọ̀ pé kò pọn dandan kí ìlà ìdílé tí Mèsáyà ti wá gba ọ̀dọ̀ àkọ́bí kọjá? (w17.12 14)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 34:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni Ẹ̀bùn ṣe kí ọ̀rọ̀ rẹ̀ lè wọ onílé lọ́kàn? Báwo la ṣe lè fi ìwé Bíbélì Kọ́ Wa bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 13)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 4 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 40

  • “Ẹ Mú Àwọn Ọlọ́run Àjèjì Kúrò”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà “Ẹ Dojú Ìjà Kọ Èṣù”.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 18 ¶14-22

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 143 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́