ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 April ojú ìwé 6
  • Àkóbá Tí Ẹgbẹ́ Búburú Máa Ń Fà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àkóbá Tí Ẹgbẹ́ Búburú Máa Ń Fà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jíjíròrò Ohun Tẹ̀mí Ń gbéni Ró
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Má Ṣe Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Ṣohun Tẹ́gbẹ́ Ń Ṣe Ní Ipa Lórí Àǹfààní Tí O Ní Láti Wàásù
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2000
  • Máa Kẹ́gbẹ́ Pẹ̀lú Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Tí Ọlọ́run Fẹ́ràn
    ‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run’
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 April ojú ìwé 6
Arákùnrin kan gbafẹ́ jáde pẹ̀lú àwọn tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́. Ó ń gbọ́ bí wọ́n ṣe ń sọ ohun tó gbà wọ́n lọ́kàn, bí aṣọ, géèmù, owó àtàwọn ẹ̀rọ ìgbàlódé, àmọ́ ohun tí wọ́n ń sọ ń kọ ọ́ lóminú.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 34-35

Àkóbá Tí Ẹgbẹ́ Búburú Máa Ń Fà

34:1, 2, 7, 25

Ó ṣeé ṣe káwọn aládùúgbò wa, àwọn tá a jọ ń ṣiṣẹ́ tàbí àwọn ọmọ iléèwé wa ní àwọn ìwà kan tó dáa, àmọ́ ṣéyẹn túmọ̀ sí pé a lè máa bá wọn kẹ́gbẹ́? Kí ló máa jẹ́ ká mọ̀ bóyá ká bá ẹnì kan kẹ́gbẹ́ tàbí ká má ṣe bẹ́ẹ̀?

  • Ṣé ẹni yìí máa mú kí n túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà?

  • Kí ni ọ̀rọ̀ ẹ̀ máa ń dá lé, kí nìyẹn sì fi hàn pé ó ṣe pàtàkì sí i?​—Mt 12:34

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé àwọn tí mò ń bá rìn ń mú kí n túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà ni tàbí wọ́n mú kí n jìnnà sí i?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́