May 4-10
JẸ́NẸ́SÍSÌ 36-37
Orin 114 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àwọn Ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù Hùwà Ìkà Sí I Torí Wọ́n Ń Jowú Rẹ̀”: (10 min.)
Jẹ 37:3, 4—Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù kórìíra rẹ̀ torí pé òun ni bàbá wọn fẹ́ràn jù (w14 8/1 12-13)
Jẹ 37:5-9, 11—Àwọn àlá tí Jósẹ́fù lá túbọ̀ mú káwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ máa jowú rẹ̀ (w14 8/1 13 ¶2-4)
Jẹ 37:23, 24, 28—Torí pé àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù ń jowú rẹ̀, wọ́n hùwà ìkà sí i
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Jẹ 36:1—Kí nìdí tí Bíbélì tún fi pe Ísọ̀ ní Édómù? (it-1 678)
Jẹ 37:29-32—Kí nìdí táwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù ṣe fi aṣọ Jósẹ́fù tó ti ya, tí ẹ̀jẹ̀ sí wà lára rẹ̀ han Jékọ́bù? (it-1 561-562)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 36:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Yéni, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 17 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w02 10/15 30-31—Àkòrí: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Káwa Kristẹni Máa Jowú Lọ́nà Tó Tọ́? (th ẹ̀kọ́ 6)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀?”: (15 min.) Ìjíròrò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Ẹ wo fídíò Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ De Àjálù? Mẹ́nu kan àwọn ìtọ́ni tí ẹ̀ka ọ́fíìsì ti fún un yín àtèyí tí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà fohùn ṣọ̀kan lé lórí, ìyẹn tó bá wà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 18 ¶23-25
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 84 àti Àdúrà